ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 37:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Lẹ́yìn náà, ó fi ògidì wúrà ṣe àwọn ohun èlò tó wà lórí tábìlì—àwọn abọ́ ìjẹun rẹ̀, àwọn ife rẹ̀, àwọn abọ́ rẹ̀ àti àwọn ṣágo tí wọ́n á máa da ọrẹ ohun mímu látinú rẹ̀.+

  • Nọ́ńbà 7:84
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 84 Èyí ni ọrẹ+ tí àwọn ìjòyè Ísírẹ́lì mú wá síbi ìyàsímímọ́ pẹpẹ nígbà tí wọ́n fòróró yàn án: abọ́ ìjẹun méjìlá (12) tí wọ́n fi fàdákà ṣe, abọ́ fàdákà méjìlá (12), ife wúrà méjìlá (12);+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́