ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 14:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ó sọ fún Júdà pé: “Ẹ jẹ́ ká kọ́ àwọn ìlú yìí, ká sì mọ ògiri àti àwọn ilé gogoro+ yí wọn ká pẹ̀lú àwọn ẹnubodè* àti àwọn ọ̀pá ìdábùú. Nítorí ilẹ̀ náà ṣì wà ní ìkáwọ́ wa, torí a ti wá Jèhófà Ọlọ́run wa. A ti wá a, ó sì ti fún wa ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá tó yí wa ká.” Torí náà, wọ́n parí àwọn ohun tí wọ́n ń kọ́.+

  • Sáàmù 1:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Ṣùgbọ́n òfin Jèhófà máa ń mú inú rẹ̀ dùn,+

      Ó sì ń fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ka* òfin Rẹ̀ tọ̀sántòru.+

       3 Ó máa dà bí igi tí a gbìn sétí odò,

      Tó ń so èso ní àsìkò rẹ̀,

      Tí ewé rẹ̀ kì í sì í rọ.

      Gbogbo ohun tó bá ń ṣe yóò máa yọrí sí rere.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́