ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 12:43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Jèhófà wá sọ fún Mósè àti Áárónì pé, “Àṣẹ tí ẹ ó máa tẹ̀ lé nígbà Ìrékọjá nìyí: Àjèjì kankan ò gbọ́dọ̀ jẹ nínú rẹ̀.+

  • Léfítíkù 23:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ìrọ̀lẹ́* ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní+ ni kí ẹ ṣe Ìrékọjá+ fún Jèhófà.

  • Diutarónómì 16:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Kí o fi ẹran Ìrékọjá rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ látinú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran,+ ní ibi tí Jèhófà yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà.+

  • 2 Kíróníkà 35:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Jòsáyà ṣe Ìrékọjá+ kan fún Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì pa ẹran Ìrékọjá náà + ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́