1 Kíróníkà 28:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+ Sáàmù 89:28, 29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Èmi yóò máa fi ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ hàn sí i títí láé,+Májẹ̀mú tí mo bá a dá kò sì ní yẹ̀ láé.+ 29 Màá fìdí àwọn ọmọ* rẹ̀ múlẹ̀ títí láé,Màá sì mú kí ìtẹ́ rẹ̀ wà títí lọ bí ọ̀run.+
5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+
28 Èmi yóò máa fi ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ hàn sí i títí láé,+Májẹ̀mú tí mo bá a dá kò sì ní yẹ̀ láé.+ 29 Màá fìdí àwọn ọmọ* rẹ̀ múlẹ̀ títí láé,Màá sì mú kí ìtẹ́ rẹ̀ wà títí lọ bí ọ̀run.+