Léfítíkù 23:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kí ẹ ka àádọ́ta (50) ọjọ́+ títí dé ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì keje, kí ẹ wá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà.+
16 Kí ẹ ka àádọ́ta (50) ọjọ́+ títí dé ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì keje, kí ẹ wá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà.+