2 Sámúẹ́lì 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nígbà náà, Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibi ààbò, wọ́n* sì pe ibẹ̀ ní Ìlú Dáfídì; Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́lé yí ká orí Òkìtì*+ àti láwọn ibòmíì nínú ìlú.+ 1 Àwọn Ọba 9:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọmọbìnrin Fáráò+ wá láti Ìlú Dáfídì+ sí ilé tirẹ̀ tí Sólómọ́nì kọ́ fún un; lẹ́yìn náà ó mọ Òkìtì.*+ 1 Àwọn Ọba 11:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ohun tó jẹ́ kó ṣọ̀tẹ̀ sí ọba ni pé: Sólómọ́nì mọ Òkìtì,*+ ó sì dí àlàfo Ìlú Dáfídì bàbá rẹ̀.+ 2 Àwọn Ọba 12:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́, àwọn ìránṣẹ́ Jèhóáṣì dìtẹ̀ mọ́ ọn,+ wọ́n sì pa á ní ilé Òkìtì,*+ ní ọ̀nà tó lọ sí Síílà.
9 Nígbà náà, Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibi ààbò, wọ́n* sì pe ibẹ̀ ní Ìlú Dáfídì; Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́lé yí ká orí Òkìtì*+ àti láwọn ibòmíì nínú ìlú.+
24 Ọmọbìnrin Fáráò+ wá láti Ìlú Dáfídì+ sí ilé tirẹ̀ tí Sólómọ́nì kọ́ fún un; lẹ́yìn náà ó mọ Òkìtì.*+