22 Ó tì mí lójú láti ní kí ọba fún wa ní àwọn ọmọ ogun àti àwọn agẹṣin láti dáàbò bò wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá lójú ọ̀nà, torí a ti sọ fún ọba pé: “Ọwọ́ rere Ọlọ́run wa wà lára gbogbo àwọn tó ń wá a,+ àmọ́ agbára rẹ̀ àti ìbínú rẹ̀ wà lórí gbogbo àwọn tó fi í sílẹ̀.”+