Sáàmù 68:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ọlọ́run yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù ní ibi mímọ́ rẹ̀* títóbi lọ́lá.+ Òun ni Ọlọ́run Ísírẹ́lì,Ẹni tó ń fún àwọn èèyàn ní okun àti agbára.+ Ẹ yin Ọlọ́run. Sáàmù 138:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní ọjọ́ tí mo pè, o dá mi lóhùn;+O mú kí n* nígboyà, o sì mú kí n lágbára.+ Àìsáyà 41:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’
35 Ọlọ́run yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù ní ibi mímọ́ rẹ̀* títóbi lọ́lá.+ Òun ni Ọlọ́run Ísírẹ́lì,Ẹni tó ń fún àwọn èèyàn ní okun àti agbára.+ Ẹ yin Ọlọ́run.
10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’