Sáàmù 29:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà yóò fún àwọn èèyàn rẹ̀ ní agbára.+ Jèhófà yóò fi àlàáfíà jíǹkí àwọn èèyàn rẹ̀.+ Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+ Àìsáyà 41:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+
10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’