ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 3:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní ọdún kejì, lẹ́yìn tí wọ́n wá sínú ilé Ọlọ́run tòótọ́ ní Jerúsálẹ́mù, ní oṣù kejì, Serubábélì ọmọ Ṣéálítíẹ́lì àti Jéṣúà ọmọ Jèhósádákì àti ìyókù àwọn arákùnrin wọn, àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì pẹ̀lú gbogbo àwọn tó jáde wá sí Jerúsálẹ́mù láti ìgbèkùn+ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà; wọ́n yan àwọn ọmọ Léfì, láti ẹni ogún (20) ọdún sókè láti jẹ́ alábòójútó lórí iṣẹ́ ilé Jèhófà.

  • Ẹ́sírà 5:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ìgbà náà ni Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì àti Jéṣúà+ ọmọ Jèhósádákì bẹ̀rẹ̀ sí í tún ilé Ọlọ́run kọ́,+ èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù; àwọn wòlíì Ọlọ́run wà pẹ̀lú wọn, wọ́n sì ń tì wọ́n lẹ́yìn.+

  • Hágáì 1:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Torí náà, Jèhófà ru ẹ̀mí+ Serubábélì ọmọ Ṣéálítíẹ́lì, gómìnà Júdà+ sókè, ó tún ru ẹ̀mí Jóṣúà+ ọmọ Jèhósádákì, àlùfáà àgbà sókè àti ẹ̀mí gbogbo àwọn tó ṣẹ́ kù nínú àwọn èèyàn náà; wọ́n wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe àtúnkọ́ ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun tó jẹ́ Ọlọ́run wọn.+

  • Sekaráyà 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó sì fi Jóṣúà + tó jẹ́ àlùfáà àgbà hàn mí, ó dúró níwájú áńgẹ́lì Jèhófà, Sátánì+ sì dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ kó lè ta kò ó.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́