-
Ẹ́sítà 3:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Wọ́n fi àwọn lẹ́tà náà rán àwọn asáréjíṣẹ́ sí gbogbo ìpínlẹ̀ tó wà lábẹ́ àṣẹ ọba, láti fi pàṣẹ pé kí wọ́n pa gbogbo àwọn Júù, kí wọ́n run wọ́n, kí wọ́n sì pa wọ́n rẹ́, lọ́mọdé lágbà, àwọn ọmọ kéékèèké àti àwọn obìnrin, lọ́jọ́ kan náà, ìyẹn lọ́jọ́ kẹtàlá oṣù kejìlá, oṣù Ádárì,+ kí wọ́n sì gba àwọn ohun ìní wọn.+
-