Jóòbù 40:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ṣó yẹ kí ẹni tó ń wá ẹ̀sùn bá Olódùmarè fa ọ̀rọ̀?+ Kí ẹni tó fẹ́ bá Ọlọ́run wí fèsì.”+ Róòmù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ta ni ọ́, ìwọ èèyàn, tí o fi ń gbó Ọlọ́run lẹ́nu?+ Ṣé ohun tí wọ́n mọ máa ń sọ fún ẹni tó mọ ọ́n pé: “Kí ló dé tí o fi mọ mí báyìí?”+
20 Ta ni ọ́, ìwọ èèyàn, tí o fi ń gbó Ọlọ́run lẹ́nu?+ Ṣé ohun tí wọ́n mọ máa ń sọ fún ẹni tó mọ ọ́n pé: “Kí ló dé tí o fi mọ mí báyìí?”+