ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 2:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Jèhófà Ọlọ́run fi erùpẹ̀+ ilẹ̀ mọ ọkùnrin, ó mí èémí ìyè+ sí ihò imú rẹ̀, ọkùnrin náà sì di alààyè.*+

  • Àìsáyà 45:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ó mà ṣe fún ẹni tó ń bá Aṣẹ̀dá rẹ̀* fa nǹkan* o,

      Torí ó dà bí àfọ́kù ìkòkò lásán

      Láàárín àwọn àfọ́kù ìkòkò míì tó wà nílẹ̀!

      Ṣé ó yẹ kí amọ̀ sọ fún Amọ̀kòkò* pé: “Kí lò ń mọ?”+

      Àbí ó yẹ kí iṣẹ́ rẹ sọ pé: “Kò ní ọwọ́”?*

  • Àìsáyà 64:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Àmọ́ ní báyìí, Jèhófà, ìwọ ni Bàbá wa.+

      Àwa ni amọ̀, ìwọ sì ni Ẹni tó mọ wá;*+

      Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa.

  • Róòmù 9:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Kí wá ni? Ṣé amọ̀kòkò ò láṣẹ lórí amọ̀+ láti fi lára ìṣùpọ̀ rẹ̀ mọ ohun èlò* kan fún ìlò tó lọ́lá, kí ó sì fi lára rẹ̀ mọ ohun èlò míì fún ìlò tí kò lọ́lá?

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́