Àìsáyà 29:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ wo bí ẹ ṣe ń dorí nǹkan kodò!* Ṣé ojú kan náà ló yẹ ká fi wo amọ̀kòkò àti amọ̀?+ Ṣé ó yẹ kí ohun tí a dá sọ nípa ẹni tó dá a pé: “Òun kọ́ ló dá mi”?+ Ṣé ohun tí a ṣe sì máa ń sọ fún ẹni tó ṣe é pé: “Kò fi òye hàn”?+ Jeremáyà 18:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “‘Ṣé mi ò lè ṣe yín bí amọ̀kòkò yìí ti ṣe ni, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì?’ ni Jèhófà wí. ‘Wò ó! Bí amọ̀ ṣe rí lọ́wọ́ amọ̀kòkò, bẹ́ẹ̀ ni ẹ rí lọ́wọ́ mi, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì.+ Róòmù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ta ni ọ́, ìwọ èèyàn, tí o fi ń gbó Ọlọ́run lẹ́nu?+ Ṣé ohun tí wọ́n mọ máa ń sọ fún ẹni tó mọ ọ́n pé: “Kí ló dé tí o fi mọ mí báyìí?”+
16 Ẹ wo bí ẹ ṣe ń dorí nǹkan kodò!* Ṣé ojú kan náà ló yẹ ká fi wo amọ̀kòkò àti amọ̀?+ Ṣé ó yẹ kí ohun tí a dá sọ nípa ẹni tó dá a pé: “Òun kọ́ ló dá mi”?+ Ṣé ohun tí a ṣe sì máa ń sọ fún ẹni tó ṣe é pé: “Kò fi òye hàn”?+
6 “‘Ṣé mi ò lè ṣe yín bí amọ̀kòkò yìí ti ṣe ni, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì?’ ni Jèhófà wí. ‘Wò ó! Bí amọ̀ ṣe rí lọ́wọ́ amọ̀kòkò, bẹ́ẹ̀ ni ẹ rí lọ́wọ́ mi, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì.+
20 Ta ni ọ́, ìwọ èèyàn, tí o fi ń gbó Ọlọ́run lẹ́nu?+ Ṣé ohun tí wọ́n mọ máa ń sọ fún ẹni tó mọ ọ́n pé: “Kí ló dé tí o fi mọ mí báyìí?”+