Jóòbù 19:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí ó dá mi lójú pé olùràpadà*+ mi wà láàyè;Ó máa wá tó bá yá, ó sì máa dìde lórí ayé.* Sáàmù 23:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí mo tilẹ̀ ń rìn nínú àfonífojì tó ṣókùnkùn biribiri,+Mi ò bẹ̀rù ewukéwu,+Nítorí o wà pẹ̀lú mi;+Ọ̀gọ* rẹ àti ọ̀pá rẹ ń fi mí lọ́kàn balẹ̀.*
4 Bí mo tilẹ̀ ń rìn nínú àfonífojì tó ṣókùnkùn biribiri,+Mi ò bẹ̀rù ewukéwu,+Nítorí o wà pẹ̀lú mi;+Ọ̀gọ* rẹ àti ọ̀pá rẹ ń fi mí lọ́kàn balẹ̀.*