Sáàmù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mi ò bẹ̀rù ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyànTí wọ́n yí mi ká láti gbógun tì mí.+ Sáàmù 27:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jèhófà ni ìmọ́lẹ̀ mi+ àti ìgbàlà mi. Ta ni èmi yóò bẹ̀rù?+ Jèhófà ni odi ààbò ayé mi.+ Ta ni èmi yóò fòyà? Àìsáyà 41:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’
27 Jèhófà ni ìmọ́lẹ̀ mi+ àti ìgbàlà mi. Ta ni èmi yóò bẹ̀rù?+ Jèhófà ni odi ààbò ayé mi.+ Ta ni èmi yóò fòyà?
10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’