Sáàmù 23:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí mo tilẹ̀ ń rìn nínú àfonífojì tó ṣókùnkùn biribiri,+Mi ò bẹ̀rù ewukéwu,+Nítorí o wà pẹ̀lú mi;+Ọ̀gọ* rẹ àti ọ̀pá rẹ ń fi mí lọ́kàn balẹ̀.* Róòmù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Kí ni ká wá sọ sọ́rọ̀ yìí? Tí Ọlọ́run bá wà lẹ́yìn wa, ta ló lè dènà wa?+ Hébérù 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+
4 Bí mo tilẹ̀ ń rìn nínú àfonífojì tó ṣókùnkùn biribiri,+Mi ò bẹ̀rù ewukéwu,+Nítorí o wà pẹ̀lú mi;+Ọ̀gọ* rẹ àti ọ̀pá rẹ ń fi mí lọ́kàn balẹ̀.*
6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+