Sáàmù 36:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ọ̀dọ̀ rẹ ni orísun ìyè wà;+Ipasẹ̀ ìmọ́lẹ̀ rẹ ni a fi lè rí ìmọ́lẹ̀.+ Sáàmù 43:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ àti òtítọ́ rẹ jáde.+ Kí wọ́n máa darí mi;+Kí wọ́n ṣamọ̀nà mi sí òkè mímọ́ rẹ àti sí àgọ́ ìjọsìn rẹ títóbi.+ Sáàmù 119:105 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 105 Ọ̀rọ̀ rẹ jẹ́ fìtílà fún ẹsẹ̀ miÀti ìmọ́lẹ̀ fún ọ̀nà mi.+
3 Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ àti òtítọ́ rẹ jáde.+ Kí wọ́n máa darí mi;+Kí wọ́n ṣamọ̀nà mi sí òkè mímọ́ rẹ àti sí àgọ́ ìjọsìn rẹ títóbi.+