Oníwàásù 9:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí àwọn alààyè mọ̀* pé àwọn máa kú,+ àmọ́ àwọn òkú kò mọ nǹkan kan rárá,+ wọn kò sì ní èrè* kankan mọ́, nítorí pé wọ́n ti di ẹni ìgbàgbé.+ Oníwàásù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, èèyàn á máa bẹ̀rù ibi tó ga, ẹ̀rù á sì wà lójú ọ̀nà. Igi álímọ́ńdì ń yọ ìtànná,+ tata ń wọ́ ara rẹ̀ lọ, àgbáyun kápérì sì bẹ́, torí pé èèyàn ń lọ sí ilé rẹ̀ ayérayé,+ àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ sì ń rìn kiri ní ojú ọ̀nà;+
5 Nítorí àwọn alààyè mọ̀* pé àwọn máa kú,+ àmọ́ àwọn òkú kò mọ nǹkan kan rárá,+ wọn kò sì ní èrè* kankan mọ́, nítorí pé wọ́n ti di ẹni ìgbàgbé.+
5 Bákan náà, èèyàn á máa bẹ̀rù ibi tó ga, ẹ̀rù á sì wà lójú ọ̀nà. Igi álímọ́ńdì ń yọ ìtànná,+ tata ń wọ́ ara rẹ̀ lọ, àgbáyun kápérì sì bẹ́, torí pé èèyàn ń lọ sí ilé rẹ̀ ayérayé,+ àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ sì ń rìn kiri ní ojú ọ̀nà;+