-
Jóòbù 1:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Bó ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, ẹlòmíì dé, ó sì sọ pé: “Àwọn ará Kálídíà+ pín ara wọn sí àwùjọ mẹ́ta, wọ́n ya bo àwọn ràkúnmí, wọ́n sì kó wọn, wọ́n wá fi idà pa àwọn ìránṣẹ́. Èmi nìkan ni mo yè bọ́, tí mo sì wá sọ fún ọ.”
-