Sáàmù 119:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Mo fi ọ̀rọ̀ rẹ ṣe ìṣúra nínú ọkàn mi+Kí n má bàa dẹ́ṣẹ̀ sí ọ.+ Sáàmù 119:127 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 127 Ìdí nìyẹn tí mo fi nífẹ̀ẹ́ àwọn àṣẹ rẹJu wúrà, kódà ju wúrà tó dára* lọ.+ Jeremáyà 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Mo rí ọ̀rọ̀ rẹ, mo sì jẹ ẹ́;+Ọ̀rọ̀ rẹ sì di ayọ̀ fún mi àti ìdùnnú ọkàn mi,Nítorí wọ́n ti fi orúkọ rẹ pè mí, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.
16 Mo rí ọ̀rọ̀ rẹ, mo sì jẹ ẹ́;+Ọ̀rọ̀ rẹ sì di ayọ̀ fún mi àti ìdùnnú ọkàn mi,Nítorí wọ́n ti fi orúkọ rẹ pè mí, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.