ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 19:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ìbẹ̀rù Jèhófà+ mọ́, ó wà títí láé.

      Àwọn ìdájọ́ Jèhófà jẹ́ òótọ́, òdodo ni wọ́n látòkè délẹ̀.+

      10 Wọ́n yẹ ní fífẹ́ ju wúrà,

      Ju ọ̀pọ̀ wúrà tó dáa,*+

      Wọ́n sì dùn ju oyin lọ,+ oyin inú afárá.

  • Sáàmù 119:72
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 72 Òfin tí o kéde dára fún mi,+

      Ó dára ju ẹgbẹẹgbẹ̀rún wúrà àti fàdákà lọ.+

  • Òwe 3:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Aláyọ̀ ni ẹni tó wá ọgbọ́n rí+

      Àti ẹni tó ní òye;

      14 Kéèyàn ní in sàn ju kéèyàn ní fàdákà,

      Kéèyàn jèrè rẹ̀ sì sàn ju kéèyàn jèrè wúrà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́