ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 119:137
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 137 Olódodo ni ọ́, Jèhófà,+

      Àwọn ìdájọ́ rẹ sì tọ́.+

  • Sáàmù 119:160
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 160 Òtítọ́ ni kókó inú ọ̀rọ̀ rẹ,+

      Gbogbo ìdájọ́ rẹ tí ó jẹ́ òdodo sì wà títí láé.

  • Ìfihàn 16:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Mo sì gbọ́ tí pẹpẹ náà sọ pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àní òótọ́ àti òdodo ni àwọn ìdájọ́* rẹ.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́