Sáàmù 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Má ṣe jẹ́ kí ìránṣẹ́ rẹ hùwà ògbójú;+Má ṣe jẹ́ kí ó jọba lé mi lórí.+ Nígbà náà, màá pé pérépéré,+Ọwọ́ mi á sì mọ́ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.* Sáàmù 37:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Òfin Ọlọ́run rẹ̀ wà ní ọkàn rẹ̀;+Ẹsẹ̀ rẹ̀ kò ní tàsé.+
13 Má ṣe jẹ́ kí ìránṣẹ́ rẹ hùwà ògbójú;+Má ṣe jẹ́ kí ó jọba lé mi lórí.+ Nígbà náà, màá pé pérépéré,+Ọwọ́ mi á sì mọ́ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.*