-
Oníwàásù 8:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Mo tún rí i tí wọ́n ń sìnkú àwọn ẹni burúkú, àwọn tó máa ń wọlé, tí wọ́n sì ń jáde ní ibi mímọ́, àmọ́ kò pẹ́ tí wọ́n fi gbàgbé wọn ní ìlú tí wọ́n ti hu irú ìwà yìí.+ Asán ni èyí pẹ̀lú.
-