Jẹ́nẹ́sísì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà Ọlọ́run fi erùpẹ̀+ ilẹ̀ mọ ọkùnrin, ó mí èémí ìyè+ sí ihò imú rẹ̀, ọkùnrin náà sì di alààyè.*+ Àìsáyà 42:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+ Ìṣe 17:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 bẹ́ẹ̀ ni kì í retí pé kí èèyàn ran òun lọ́wọ́ bíi pé ó nílò ohunkóhun,+ nítorí òun fúnra rẹ̀ ló ń fún gbogbo èèyàn ní ìyè àti èémí+ àti ohun gbogbo.
7 Jèhófà Ọlọ́run fi erùpẹ̀+ ilẹ̀ mọ ọkùnrin, ó mí èémí ìyè+ sí ihò imú rẹ̀, ọkùnrin náà sì di alààyè.*+
5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+
25 bẹ́ẹ̀ ni kì í retí pé kí èèyàn ran òun lọ́wọ́ bíi pé ó nílò ohunkóhun,+ nítorí òun fúnra rẹ̀ ló ń fún gbogbo èèyàn ní ìyè àti èémí+ àti ohun gbogbo.