ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 41:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 “Ṣé o lè fi ìwọ ẹja mú Léfíátánì,*+

      Àbí o lè fi okùn de ahọ́n rẹ̀ mọ́lẹ̀?

  • Jóòbù 41:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Kò sí ẹni tó jẹ́ ru ú sókè.

      Ta ló wá lè kò mí lójú?+

  • Sáàmù 104:25, 26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ibẹ̀ ni òkun wà, ó tóbi, ó sì fẹ̀,

      Àìmọye ohun alààyè ló wà nínú rẹ̀, èyí tó kéré àti èyí tó tóbi.+

      26 Ibẹ̀ ni àwọn ọkọ̀ òkun ti ń rìn

      Àti Léfíátánì,*+ tí o dá kí ó lè máa ṣeré nínú rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́