ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,

      Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀.

      Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+

      Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+

  • Sáàmù 33:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ó nífẹ̀ẹ́ òdodo àti ìdájọ́ òdodo.+

      Ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ kún inú ayé.+

  • Sáàmù 37:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Nítorí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo,

      Kò sì ní kọ àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀ sílẹ̀.+

      ע [Áyìn]

      Ìgbà gbogbo ni yóò máa ṣọ́ wọn;+

      Àmọ́ a ó pa àtọmọdọ́mọ àwọn ẹni burúkú rẹ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́