Émọ́sì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹni tó dá àgbájọ ìràwọ̀ Kímà* àti àgbájọ ìràwọ̀ Késílì,*+Ẹni tó ń sọ òkùnkùn biribiri di ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Ẹni tó ń mú kí ọ̀sán ṣókùnkùn bí òru,+Ẹni tó ń wọ́ omi jọ látinú òkunKí ó lè dà á sórí ilẹ̀,+Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.
8 Ẹni tó dá àgbájọ ìràwọ̀ Kímà* àti àgbájọ ìràwọ̀ Késílì,*+Ẹni tó ń sọ òkùnkùn biribiri di ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Ẹni tó ń mú kí ọ̀sán ṣókùnkùn bí òru,+Ẹni tó ń wọ́ omi jọ látinú òkunKí ó lè dà á sórí ilẹ̀,+Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.