ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 9:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ó ṣe àgbájọ ìràwọ̀ Ááṣì,* Késílì* àti Kímà,*+

      Pẹ̀lú àgbájọ ìràwọ̀ apá gúúsù ojú ọ̀run;*

  • Jóòbù 38:31-33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Ṣé o lè so àwọn okùn àgbájọ ìràwọ̀ Kímà,*

      Àbí o lè tú àwọn okùn àgbájọ ìràwọ̀ Késílì?*+

      32 Ṣé o lè kó àgbájọ ìràwọ̀* jáde ní àsìkò rẹ̀,

      Àbí o lè darí àgbájọ ìràwọ̀ Ááṣì* pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀?

      33 Ṣé o mọ àwọn òfin tó ń darí ojú ọ̀run,+

      Àbí o lè fipá mú kí ayé tẹ̀ lé àwọn àṣẹ wọn?*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́