ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 104:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àwọn ọmọ kìnnìún* ń ké ramúramù nítorí ẹran tí wọ́n fẹ́ pa jẹ,+

      Wọ́n sì ń wá oúnjẹ wọn lọ́dọ̀ Ọlọ́run.+

  • Sáàmù 145:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ojú rẹ ni gbogbo ẹ̀dá ń wò,

      Ò ń fún wọn ní oúnjẹ wọn lásìkò.+

      פ [Péè]

      16 O ṣí ọwọ́ rẹ,

      O sì fún gbogbo ohun alààyè ní ohun tí wọ́n ń fẹ́.+

  • Náhúmù 2:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Kìnnìún ń fa ọ̀pọ̀ ẹran ya fún àwọn ọmọ rẹ̀

      Ó sì ń fún ẹran lọ́rùn pa fún àwọn abo rẹ̀.

      Ó kó ẹran tí ó pa kún inú ihò rẹ̀,

      Àti èyí tó fà ya kún ibùgbé rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́