Sáàmù 104:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Gbogbo wọn ń dúró dè ọ́Kí o lè fún wọn ní oúnjẹ lásìkò.+ 28 Ohun tí o fún wọn ni wọ́n ń kó jọ.+ Tí o bá ṣí ọwọ́ rẹ, wọ́n á ní ọ̀pọ̀ ohun rere ní ànító.+ Sáàmù 107:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí ó mú kí àwọn tí òùngbẹ ń gbẹ mu àmutẹ́rùn,Ó sì mú kí àwọn* tí ebi ń pa jẹ ohun rere ní àjẹtẹ́rùn.+ Sáàmù 132:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Ibi ìsinmi mi títí láé nìyí;Ibí ni màá máa gbé,+ nítorí ohun tí mo fẹ́ nìyẹn. 15 Màá fi ọ̀pọ̀ oúnjẹ kún ibẹ̀;Màá fi oúnjẹ tẹ́ àwọn aláìní ibẹ̀ lọ́rùn.+
27 Gbogbo wọn ń dúró dè ọ́Kí o lè fún wọn ní oúnjẹ lásìkò.+ 28 Ohun tí o fún wọn ni wọ́n ń kó jọ.+ Tí o bá ṣí ọwọ́ rẹ, wọ́n á ní ọ̀pọ̀ ohun rere ní ànító.+
9 Nítorí ó mú kí àwọn tí òùngbẹ ń gbẹ mu àmutẹ́rùn,Ó sì mú kí àwọn* tí ebi ń pa jẹ ohun rere ní àjẹtẹ́rùn.+
14 “Ibi ìsinmi mi títí láé nìyí;Ibí ni màá máa gbé,+ nítorí ohun tí mo fẹ́ nìyẹn. 15 Màá fi ọ̀pọ̀ oúnjẹ kún ibẹ̀;Màá fi oúnjẹ tẹ́ àwọn aláìní ibẹ̀ lọ́rùn.+