Sekaráyà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó sì fi Jóṣúà + tó jẹ́ àlùfáà àgbà hàn mí, ó dúró níwájú áńgẹ́lì Jèhófà, Sátánì+ sì dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ kó lè ta kò ó. Mátíù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀mí wá darí Jésù lọ sínú aginjù kí Èṣù+ lè dán an wò.+ Mátíù 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Adánniwò náà+ wá bá a, ó sì sọ fún un pé: “Tí o bá jẹ́ ọmọ Ọlọ́run, sọ fún àwọn òkúta yìí pé kí wọ́n di búrẹ́dì.” Lúùkù 22:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Símónì, Símónì, wò ó! Sátánì ti béèrè pé òun fẹ́ gba gbogbo yín, kó lè kù yín bí àlìkámà.*+ Jòhánù 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wọ́n ń jẹ oúnjẹ alẹ́ lọ́wọ́, Èṣù sì ti fi sínú ọkàn Júdásì Ìsìkáríọ́tù,+ ọmọ Símónì, pé kó dà á.+ Ìfihàn 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 A wá ju dírágónì ńlá+ náà sísàlẹ̀, ejò àtijọ́ náà,+ ẹni tí à ń pè ní Èṣù+ àti Sátánì,+ tó ń ṣi gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé lọ́nà;+ a jù ú sí ayé,+ a sì ju àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ sísàlẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀.
3 Ó sì fi Jóṣúà + tó jẹ́ àlùfáà àgbà hàn mí, ó dúró níwájú áńgẹ́lì Jèhófà, Sátánì+ sì dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ kó lè ta kò ó.
3 Adánniwò náà+ wá bá a, ó sì sọ fún un pé: “Tí o bá jẹ́ ọmọ Ọlọ́run, sọ fún àwọn òkúta yìí pé kí wọ́n di búrẹ́dì.”
9 A wá ju dírágónì ńlá+ náà sísàlẹ̀, ejò àtijọ́ náà,+ ẹni tí à ń pè ní Èṣù+ àti Sátánì,+ tó ń ṣi gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé lọ́nà;+ a jù ú sí ayé,+ a sì ju àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ sísàlẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀.