Jóòbù 1:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọkùnrin kan wà ní ilẹ̀ Úsì tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jóòbù.*+ Olódodo àti olóòótọ́* èèyàn+ ni; ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú.+ 2 Ó bí ọmọkùnrin méje àti ọmọbìnrin mẹ́ta.
1 Ọkùnrin kan wà ní ilẹ̀ Úsì tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jóòbù.*+ Olódodo àti olóòótọ́* èèyàn+ ni; ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú.+ 2 Ó bí ọmọkùnrin méje àti ọmọbìnrin mẹ́ta.