Sáàmù 49:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ wọn,+Tí wọ́n sì ń fi ọrọ̀ rẹpẹtẹ wọn fọ́nnu,+ 7 Kò sí ìkankan nínú wọn tó lè ra arákùnrin kan pa dàTàbí tí ó lè fún Ọlọ́run ní ìràpadà nítorí rẹ̀,+ Òwe 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹni tó bá gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ rẹ̀ máa ṣubú,+Àmọ́ olódodo máa rú yọ bí ewé tútù.+
6 Àwọn tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ wọn,+Tí wọ́n sì ń fi ọrọ̀ rẹpẹtẹ wọn fọ́nnu,+ 7 Kò sí ìkankan nínú wọn tó lè ra arákùnrin kan pa dàTàbí tí ó lè fún Ọlọ́run ní ìràpadà nítorí rẹ̀,+ Òwe 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹni tó bá gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ rẹ̀ máa ṣubú,+Àmọ́ olódodo máa rú yọ bí ewé tútù.+