Sáàmù 7:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá yin Jèhófà nítorí òdodo rẹ̀,+Màá sì fi orin yin* orúkọ Jèhófà+ Ẹni Gíga Jù Lọ.+ Sáàmù 52:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Èmi yóò máa yìn ọ́ títí láé torí pé o ti gbé ìgbésẹ̀;+Níwájú àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ,Màá gbẹ́kẹ̀ lé orúkọ rẹ,+ nítorí ó dára.
9 Èmi yóò máa yìn ọ́ títí láé torí pé o ti gbé ìgbésẹ̀;+Níwájú àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ,Màá gbẹ́kẹ̀ lé orúkọ rẹ,+ nítorí ó dára.