Diutarónómì 33:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ọlọ́run jẹ́ ibi ààbò láti ìgbà àtijọ́,+Ọwọ́ ayérayé rẹ̀ wà lábẹ́ rẹ.+ Ó máa lé ọ̀tá kúrò níwájú rẹ,+Ó sì máa sọ pé, ‘Pa wọ́n run!’+ Sáàmù 90:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+
27 Ọlọ́run jẹ́ ibi ààbò láti ìgbà àtijọ́,+Ọwọ́ ayérayé rẹ̀ wà lábẹ́ rẹ.+ Ó máa lé ọ̀tá kúrò níwájú rẹ,+Ó sì máa sọ pé, ‘Pa wọ́n run!’+ Sáàmù 90:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+
2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+