ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 19:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Nígbà tó yá, Sọ́ọ̀lù bá Jónátánì ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sọ̀rọ̀ lórí bó ṣe máa pa Dáfídì.+

  • Sáàmù 10:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ó ń dúró níbi tó fara pa mọ́ sí bíi kìnnìún nínú ihò rẹ̀.*+

      Ó ń dúró láti mú ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́.

      Ó ń mú ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́ nígbà tó bá pa àwọ̀n rẹ̀ dé.+

  • Sáàmù 71:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí mi,

      Àwọn tó sì fẹ́ gba ẹ̀mí* mi gbìmọ̀ pọ̀,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́