Sáàmù 37:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹni burúkú ń dìtẹ̀ olódodo;+Ó ń wa eyín pọ̀ sí i. 13 Àmọ́ Jèhófà yóò fi í rẹ́rìn-ín,Nítorí Ó mọ̀ pé ọjọ́ rẹ̀ máa dé.+
12 Ẹni burúkú ń dìtẹ̀ olódodo;+Ó ń wa eyín pọ̀ sí i. 13 Àmọ́ Jèhófà yóò fi í rẹ́rìn-ín,Nítorí Ó mọ̀ pé ọjọ́ rẹ̀ máa dé.+