Sáàmù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà yóò di ibi ààbò* fún àwọn tí à ń ni lára,+Ibi ààbò ní àkókò wàhálà.+ Sáàmù 62:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní tòótọ́, òun ni àpáta mi àti ìgbàlà mi, ibi ààbò mi;*+Mìmì kan ò ní mì mí débi tí màá ṣubú.+