ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 37:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ó kọjá agbára wa láti lóye Olódùmarè;+

      Agbára rẹ̀ pọ̀ gan-an,+

      Kì í ṣe ohun tó lòdì sí ìdájọ́ òdodo+ rẹ̀ àti òdodo rẹ̀ tó pọ̀ gidigidi.+

  • Sáàmù 21:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Dìde nínú agbára rẹ, Jèhófà.

      A ó fi orin yin* agbára ńlá rẹ.

  • Sáàmù 145:10-12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Jèhófà, gbogbo iṣẹ́ rẹ yóò máa yìn ọ́ lógo,+

      Àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ yóò sì máa yìn ọ́.+

      כ [Káfì]

      11 Wọ́n á máa kéde ògo ìjọba rẹ,+

      Wọ́n á sì máa sọ̀rọ̀ nípa agbára rẹ,+

      ל [Lámédì]

      12 Kí aráyé lè mọ àwọn iṣẹ́ ńlá rẹ+

      Àti ògo ọlá ńlá ìjọba rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́