ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 18:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 O fún mi ní apata rẹ láti gbà mí là,+

      Ọwọ́ ọ̀tún rẹ ń tì mí lẹ́yìn,*

      Ìrẹ̀lẹ̀ rẹ sì sọ mí di ẹni ńlá.+

  • Sáàmù 21:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ọwọ́ rẹ á tẹ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ;

      Ọwọ́ ọ̀tún rẹ á tẹ àwọn tó kórìíra rẹ.

  • Sáàmù 108:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Kí a lè gba àwọn olùfẹ́ rẹ sílẹ̀,

      Fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ gbà wá sílẹ̀, kí o sì dá mi lóhùn.+

  • Sáàmù 118:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ìró ayọ̀ àti ti ìgbàlà*

      Wà ní àgọ́ àwọn olódodo.

      Ọwọ́ ọ̀tún Jèhófà ń fi agbára rẹ̀ hàn.+

  • Àìsáyà 41:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+

      Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+

      Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+

      Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́