Sáàmù 10:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ Jèhófà, wàá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Wàá mú ọkàn wọn dúró ṣinṣin,+ wàá sì fiyè sí wọn.+ Sáàmù 102:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Á fetí sí àdúrà àwọn òtòṣì,+Kò sì ní kó àdúrà wọn dà nù.+ Àìsáyà 66:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ọwọ́ mi ni ó ṣe gbogbo nǹkan yìí,Bí gbogbo wọn sì ṣe wà nìyí,” ni Jèhófà wí.+ “Màá wá wo ẹni yìí,Ẹni tó rẹlẹ̀, tí ìbànújẹ́ sì bá ọkàn rẹ̀, tó ń gbọ̀n rìrì* nítorí ọ̀rọ̀ mi.+
17 Àmọ́ Jèhófà, wàá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Wàá mú ọkàn wọn dúró ṣinṣin,+ wàá sì fiyè sí wọn.+
2 “Ọwọ́ mi ni ó ṣe gbogbo nǹkan yìí,Bí gbogbo wọn sì ṣe wà nìyí,” ni Jèhófà wí.+ “Màá wá wo ẹni yìí,Ẹni tó rẹlẹ̀, tí ìbànújẹ́ sì bá ọkàn rẹ̀, tó ń gbọ̀n rìrì* nítorí ọ̀rọ̀ mi.+