Sáàmù 35:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà náà, ahọ́n mi yóò máa ròyìn* òdodo rẹ,+Yóò sì máa yìn ọ́ láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.+ Sáàmù 40:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mo kéde ìhìn rere òdodo nínú ìjọ ńlá.+ Wò ó! Mi ò pa ẹnu mi mọ́,+Bí ìwọ náà ṣe mọ̀ dáadáa, Jèhófà.