Sáàmù 53:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà àìtọ́ wọn burú, ó sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+
53 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà àìtọ́ wọn burú, ó sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+