Sáàmù 42:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí nìdí tí ìrẹ̀wẹ̀sì fi bá ẹ̀mí* mi?+ Kí nìdí tí ìdààmú fi bá ọkàn mi? Dúró de Ọlọ́run,+Nítorí mo ṣì máa yìn ín torí òun ni Olùgbàlà mi Atóbilọ́lá.+
5 Kí nìdí tí ìrẹ̀wẹ̀sì fi bá ẹ̀mí* mi?+ Kí nìdí tí ìdààmú fi bá ọkàn mi? Dúró de Ọlọ́run,+Nítorí mo ṣì máa yìn ín torí òun ni Olùgbàlà mi Atóbilọ́lá.+