Sáàmù 79:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà, ìgbà wo lo máa bínú dà? Ṣé títí láé ni?+ Ìgbà wo ni ìbínú ńlá rẹ máa jó bí iná dà?+