Sáàmù 98:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+
98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+