Àìsáyà 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa sọ pé: “Wò ó! Ọlọ́run wa nìyí!+ A ti gbẹ́kẹ̀ lé e,+Ó sì máa gbà wá là.+ Jèhófà nìyí! A ti gbẹ́kẹ̀ lé e. Ẹ jẹ́ ká máa yọ̀, kí inú wa sì dùn torí ìgbàlà rẹ̀.”+
9 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa sọ pé: “Wò ó! Ọlọ́run wa nìyí!+ A ti gbẹ́kẹ̀ lé e,+Ó sì máa gbà wá là.+ Jèhófà nìyí! A ti gbẹ́kẹ̀ lé e. Ẹ jẹ́ ká máa yọ̀, kí inú wa sì dùn torí ìgbàlà rẹ̀.”+