Sáàmù 37:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀,Yóò gbé ọ ga láti jogún ayé. Nígbà tí a bá pa àwọn ẹni burúkú rẹ́,+ wàá rí i.+ Sáàmù 146:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Aláyọ̀ ni ẹni tí Ọlọ́run Jékọ́bù jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀,+Tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,+
34 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀,Yóò gbé ọ ga láti jogún ayé. Nígbà tí a bá pa àwọn ẹni burúkú rẹ́,+ wàá rí i.+